Odutola sọ pe iwadii n tẹsiwaju lori isẹlẹ ọhun. O ni awọn ti taari ọrọ naa si ẹka to n ri si iwadii ẹsun ọdaran. ''Awọn ọdẹ marun-un naa ti wa lakata ọlọpaa ...